2 Ọba 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ní ti gbogbo àwọn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà ìjọba Áhásáyà, àti ohun tí ó ṣe, ṣe a kò ha kọ wọ́n sí inú ìwé ọdọọdún ti àwọn ọba Ísírẹ́lì?

2 Ọba 1

2 Ọba 1:8-18