2 Ọba 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, iná ti sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run láti jó àwọn balógun méjì àràádọ́ta àkọ́kọ́ pẹ̀lú àràádọ́ta wọn. Ṣùgbọ́n Nísinsìn yìí ní ojúrere fún ẹ̀mí mi!”

2 Ọba 1

2 Ọba 1:4-18