2 Kọ́ríńtì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn tìkárawọn pẹ̀lú ẹ̀bẹ̀ fún un yín ń ṣe àfẹ́rí yín nítorí ọ̀pọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ti ń bẹ nínú yín.

2 Kọ́ríńtì 9

2 Kọ́ríńtì 9:12-15