2 Kọ́ríńtì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwa ní ìgboyà nígbà gbogbo, àwa sì mọ̀ pé, nígbà tí àwa ń bẹ ní ilé nínú ara, àwa kò sí lọ́dọ̀ Olúwa.

2 Kọ́ríńtì 5

2 Kọ́ríńtì 5:2-7