2 Kọ́ríńtì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àwọn ẹni tí Ọlọ́run ayé yìí ti sọ ọkàn àwọn aláìgbàgbọ́ dí afọ́jú, kí ìmọ́lẹ̀ ìyìn rere Kírísítì tí ó lógo, ẹni tí í ṣe àworán Ọlọ́run, má ṣe mọ́lẹ̀ nínú wọn.

2 Kọ́ríńtì 4

2 Kọ́ríńtì 4:1-8