2 Kọ́ríńtì 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni àárẹ̀ kò ṣe mú wa; ṣùgbọ́n bí ọkùnrin ti òde wa bá ń parun, ṣíbẹ̀ ọkùnrin tí inú wa ń di túntún lójoojúmọ́.

2 Kọ́ríńtì 4

2 Kọ́ríńtì 4:13-18