2 Kọ́ríńtì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í sì í ṣe bí Mósè, ẹni tí ó fí ìbòjú bo ojú rẹ̀, ki àwọn ọmọ Ísríẹ́lì má baà lè tẹjú mọ wíwo òpin èyí tí ń kọjá lọ

2 Kọ́ríńtì 3

2 Kọ́ríńtì 3:4-17