2 Kọ́ríńtì 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore ọ̀fẹ́ Jésù Kírísítì Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín. (Àmín).

2 Kọ́ríńtì 13

2 Kọ́ríńtì 13:6-14