2 Kọ́ríńtì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo di òmùgọ̀ nípa ṣíṣògo; ẹ̀yin ní ó fí ipá mú mi ṣe é: nítorí tí ó tọ́ tí ẹ bá yìn mí: nítorí tí èmi kò rẹ̀yìn lóhunkóhun sí àwọn àgbà Àpósítélì bí èmi kò tilẹ̀ jámọ́ nǹkan kan.

2 Kọ́ríńtì 12

2 Kọ́ríńtì 12:6-16