2 Kọ́ríńtì 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo tilẹ̀ jẹ́ òpè nínú ọ̀rọ̀ sísọ, kì í ṣe nínú ìmọ̀; Ní ọ̀nàkọnà ni àwa ti fi èyí hàn dájúdájú fún yín nínú ohun gbogbo.

2 Kọ́ríńtì 11

2 Kọ́ríńtì 11:1-15