2 Kọ́ríńtì 11:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Dámásíkù, baálẹ̀ tí ó wà lábẹ́ ọba Árétà fí ẹgbẹ́ ogun ká ìlú àwọn ara Dámásíkù mọ́, ó ń fẹ́ mi láti mú:

2 Kọ́ríńtì 11

2 Kọ́ríńtì 11:29-33