2 Kọ́ríńtì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú làálàá àti ìrora, nínú ìṣọ́-òru nígbákùúgbà, nínú ebi àti òrùgbẹ, nínú ààwẹ̀ nígbákùúgbà, nínú òtútù àti ìhòòhò.

2 Kọ́ríńtì 11

2 Kọ́ríńtì 11:24-33