2 Kọ́ríńtì 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hébérù ni wọ́n bí? Bẹ́ẹ̀ ni èmi. Ísírẹ́lì ni wọ́n bí? Bẹ́ẹ̀ ni èmi. Irú ọmọ Ábúráhámù ní òun bí? Bẹ́ẹ̀ ni èmi.

2 Kọ́ríńtì 11

2 Kọ́ríńtì 11:18-27