2 Kọ́ríńtì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rò wí pé ẹ ó farada díẹ̀ nínú ìwà òmùgọ̀ mi ṣùgbọ́n ẹ tilẹ̀ ti rí ṣe bẹ́ẹ̀.

2 Kọ́ríńtì 11

2 Kọ́ríńtì 11:1-11