2 Kọ́ríńtì 10:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kò ṣògo rékọjá ààlà wa, èyí nì, lórí iṣẹ́ elòmiràn, ṣùgbọ́n àwa ní ìrètí pé, bí ìgbàgbọ́ yín ti ń dàgbà sí i, gẹ́gẹ́ bí ààlà wa, àwa ó dí gbígbéga lọ́dọ̀ yín sí i lọ́pọ̀lọpọ̀.

2 Kọ́ríńtì 10

2 Kọ́ríńtì 10:5-18