2 Kọ́ríńtì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùbùkún ni Ọlọ́run, àti Baba Jésù Kírísítì Olúwa wa, Baba ìyọ́nú, àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo;

2 Kọ́ríńtì 1

2 Kọ́ríńtì 1:1-12