2 Kọ́ríńtì 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì fí èdìdì rẹ̀ dì wá pẹ̀lú, ó sì tí fi Ẹ̀mí rẹ́ sí wa ní ọkàn gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí ìdánilójú ohun tí ó ń bọ̀.

2 Kọ́ríńtì 1

2 Kọ́ríńtì 1:18-24