2 Kíróníkà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni inú àwọn ọkùnrin rẹ ìbá ṣe dùn tó! Báwó nínú dídùn àwọn ìránṣẹ́ rẹ, àwọn tí n dúró nígbà gbogbo níwájú rẹ láti gbọ́ ọgbọ́n rẹ!

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:1-8