2 Kíróníkà 9:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gẹ́gẹ́ bí ìyókù iṣẹ́ ìjọba Sólómónì, láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn Nátanì wòlíì, àti nínú ìsọtẹ́lẹ̀ Áhíjà ará Sílónì àti nínú ìran Ídò, wòlíì tí o kan Jéróbámù ọmọ Nébátì?

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:20-31