2 Kíróníkà 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì ṣe fàdákà gẹ́gẹ́ bí ìwọpọ̀ ní Jérúsálẹ́mù gẹ́gẹ́ bí òkúta àti igi kédárì ó sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí igi síkámórè ni ibi pẹ̀tẹ́lẹ̀ gígi.

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:19-31