2 Kíróníkà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ti ṣe ọ̀ọ́dúnrún (300) kékeré ṣékélì tí a fi òlù lù wúrà, pẹ̀lú ọ̀ọ́dúnrún (3,000) sékélì wúrà nínú àpáta kọ̀kan. Ọba sì kó wọn sínú ilé ti igbó Lébánónì.

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:9-21