2 Kíróníkà 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Sólómónì fún ayaba Ṣébà ní gbogbo ohun tí ó bèèrè fún àti ohun tí ó wù ú; ó sì fi fún un ju èyí tí ó mú wá fún un lọ. Nígbà náà ni ó lọ ó sì padà pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sí ìlú rẹ̀.

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:2-15