2 Kíróníkà 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni wí pé, àwọn ọmọ wọn tí ó kù sílé ní ilẹ̀ náà, tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò parun àwọn ni Sólómónì bu iṣẹ́ ìrú fún títí di òní yìí.

2 Kíróníkà 8

2 Kíróníkà 8:7-12