2 Kíróníkà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì tún ìlú tí Hírámù ti fi fún un kọ́, ó sì kó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ níbẹ̀ kí wọn kí ó lè máa gbé nínú ibẹ̀.

2 Kíróníkà 8

2 Kíróníkà 8:1-5