2 Kíróníkà 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Húrámù sì fi ọ̀kọ̀ ránsẹ́ sì i nípa àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn ọkùnrin tí ó mòye òkun. Èyí pẹ̀lú àwọn ènìyàn Sólómónì, lọ sí Ófírì wọ́n sì gbé àádọ́ta irinwó tálẹ́ntì wúrà wá, padà èyí tí wọ́n sì mú tọ ọba Sólómónì wá.

2 Kíróníkà 8

2 Kíróníkà 8:15-18