2 Kíróníkà 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí mo bá sé ọ̀run kí ó ma báà sí òjò, tàbí láti pàsẹ fún eṣú láti jẹ ilẹ̀ náà run tàbí rán àjàkálẹ̀-àrùn sí àárin àwọn ènìyàn mi,

2 Kíróníkà 7

2 Kíróníkà 7:12-21