2 Kíróníkà 6:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí àwọn ènìyàn rẹ bá lọ sójú ogun lórí àwọn ọ̀ta wọn, nígbàkígbà tí o bá rán wọn, tí wọ́n sì gbàdúrà sí ọ lórí ìlú yìí tí ìwọ ti yàn àti ilé Olúwa tí èmi ti kọ́ fún orúkọ rẹ.

2 Kíróníkà 6

2 Kíróníkà 6:27-39