2 Kíróníkà 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ojú rẹ kí ó lè sí sí ilé Olúwa ní ọ̀sán àti lóru, ní ibí yìí tí ìwọ ti wí pé ìwọ yóò fi orúkọ rẹ síbẹ̀. Kí ìwọ kí ó gbọ́ àdúrà tí ìránṣẹ́ rẹ ń gbà lórí ibí yìí.

2 Kíróníkà 6

2 Kíróníkà 6:10-27