2 Kíróníkà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ tí o pa ìlérí tí o ṣe pẹ̀lú ìránṣẹ́ rẹ Dáfídì baba mi mọ́; nítorí ìwọ ti fi ẹnu rẹ ṣe ìlérí àti pé ìwọ ti fi ọwọ́ rẹ mú un ṣẹ; bí ó ti rí lónìí yìí.

2 Kíróníkà 6

2 Kíróníkà 6:11-21