2 Kíróníkà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà naà ni Sólómónì dúró níwájú pẹpẹ Olúwa, ní iwájú gbogbo ìjọ ènìyàn Isírẹ́lì, ó sì tẹ́ ọwọ́ọ rẹ̀ méjèèjì.

2 Kíróníkà 6

2 Kíróníkà 6:5-21