2 Kíróníkà 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn àlùfáà kò leè ṣiṣẹ́ ìsìn wọn nítorí ìkùku náà, nítorí ògo Olúwa kún inú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run.

2 Kíróníkà 5

2 Kíróníkà 5:5-14