2 Kíróníkà 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣé tábìlì mẹ́wàá, ó sì gbé wọn sí inú ilé Olúwa, márùn un ní gúṣù àti márùn ún ní ìhà àríwá. Ó ṣé ọgọ́rún ọpọ́n ìbùwọ̀n wúrà.

2 Kíróníkà 4

2 Kíróníkà 4:3-11