2 Kíróníkà 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba dà wọ́n ní ilẹ̀ amọ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jọ́dánì ní àárin méjì Súkótì àti Ṣárétánì.

2 Kíróníkà 4

2 Kíróníkà 4:10-22