2 Kíróníkà 36:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Éjíbítì lé e kúrò lórí ìtẹ́ ní Jérúsálẹ́mù ó sì bù fún un lórí Júdà, ọgọ́rún talẹ́ńtì fàdákà (100) àti talẹ́ntì wúrà kan.

2 Kíróníkà 36

2 Kíróníkà 36:2-12