2 Kíróníkà 36:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlẹ̀ náà sì gbádùn ìsinmi rẹ̀, ní gbogbo ìgbà ìdahoro, òun sì ń sinmi títí ó fi di àádọ́rin ọdún (70) fi pé ní ìmúsẹ ọ̀rọ̀ Olúwa tí a sọ láti ẹnu Jeremíà.

2 Kíróníkà 36

2 Kíróníkà 36:11-23