2 Kíróníkà 36:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú gbogbo ohun èlò láti ilé Ọlọ́run lọ sí Bábílónì, níńlá àti kékeré àti ìṣúra ilé Olúwa àti ìṣúra ọba àti ìjòyè rẹ̀.

2 Kíróníkà 36

2 Kíróníkà 36:16-19