2 Kíróníkà 35:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú síi, Jósíà ṣe ìrántí àjọ ìrékọjá sí Olúwa ní Jérúsálẹ́mù, Àjọ ìrékọjá náà ni wọ́n sì pa ẹran ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìn-ní-ní.

2 Kíróníkà 35

2 Kíróníkà 35:1-10