2 Kíróníkà 34:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún ọba Júdà, ẹni tí ó rán yín láti bèèrè lọ́wọ́ Olúwa, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa ti sọ, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nípa ọ̀rọ̀ wọ̀n nì tí íwọ gbọ́:

2 Kíróníkà 34

2 Kíróníkà 34:25-32