2 Kíróníkà 34:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósíà sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́jọ nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì dí ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31).

2 Kíróníkà 34

2 Kíróníkà 34:1-7