2 Kíróníkà 33:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánásè jẹ́ ọmọ ọdún Méjìlá nígbà tí ó di ọba. Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún márùndínlọ́gọ́ta.

2 Kíróníkà 33

2 Kíróníkà 33:1-8