2 Kíróníkà 32:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára ẹran ara nìkan ni ó wà pẹ̀lú rẹ̀ ṣùgbọ́n, pẹ̀lú wa ni Ọlọ́run láti ràn wá lọ́wọ́ àti láti ja ìjà wa.” Àwọn ènìyàn sì ní ìgboyà láti ara ohun tí Hesekía ọba Júdà wí.

2 Kíróníkà 32

2 Kíróníkà 32:1-11