2 Kíróníkà 32:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekíà ni ó dí ojú ìṣúra apá òkè ti orísun Gíhónì. Ó sì gbe gba ìsàlẹ̀ sí ìhà ìwọ oòrùn ìlú ńlá ti Dáfídì. Ó ṣe àṣeyọrí sí rere nínu gbogbo ohun tí ó dáwọ́lé.

2 Kíróníkà 32

2 Kíróníkà 32:23-33