2 Kíróníkà 32:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekáyà ní ọ̀pọ̀ ọrọ̀ ńlá àti ọlá, Ó sì ṣe àwọn ilé ìṣúra fún fàdákà àti wúrà rẹ̀ àti fún àwọn òkúta iyebíye rẹ̀, àwọn tùràrí olóòórùn dídùn àwọn àpáta àti gbogbo oríṣìí nǹkan iyebíye.

2 Kíróníkà 32

2 Kíróníkà 32:22-33