2 Kíróníkà 32:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Heṣekáyà àti wòlíì Àìṣáyà ọmọ Ámósì sunkún jáde nínú àdúrà sí ọ̀run nípa èyí.

2 Kíróníkà 32

2 Kíróníkà 32:14-30