2 Kíróníkà 32:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé Heṣekáyà fún ra rẹ̀ kò mú àwọn ọlọ́run ibi gíga àti àwọn pẹpẹ kúrò, tí ó ń wí fún Júdà àti Jérúsálẹ́mù pé ‘Ẹ̀yin gbọdọ̀ sìn níwájú pẹpẹ kan àti láti sun àwọn ẹbọ lóri rẹ̀’?

2 Kíróníkà 32

2 Kíróníkà 32:6-16