2 Kíróníkà 31:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pàsẹ fún àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Jerúsálẹ́mù láti fi ìpín tí ó yẹ fún àlùfáà fún un àti àwọn ará Léfì, kí wọn kí ó lè fi ara wọn jìn fún òfin Olúwa.

2 Kíróníkà 31

2 Kíróníkà 31:2-11