2 Kíróníkà 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ohun gbogbo tí ó dáwọ́lé níti iṣẹ́ ìsìn nínú ilé Ọlọ́run àti ní ìgbọ́ràn sí òfin àti àwọn àṣẹ. Ó wá Ọlọ́run rẹ̀, ó sì ṣiṣẹ́ tọkàntọkàn. Ó sì ṣe rere.

2 Kíróníkà 31

2 Kíróníkà 31:20-21