2 Kíróníkà 31:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Édẹ́nì, Miníámínì, Jéṣúà, Ṣemáyà, Ámáríyà àti Ṣekánáyà ràn án lọ́wọ́ tọkàntọkàn nínú àwọn ìlú àwọn àlùfáà tí ń dáwó fún àwọn àlùfáà ẹlẹ́gbẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn, àgbà àti kékeré.

2 Kíróníkà 31

2 Kíróníkà 31:8-18