2 Kíróníkà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyẹ́ apá àwọn kérúbù wọ̀nyìí gbà tó ogún ìgbọ̀nwọ́. Wọ́n dúró ní ẹsẹ̀ wọn, wọ́n kọjú sí yàrá pàtàkì ńlá naà.

2 Kíróníkà 3

2 Kíróníkà 3:4-17