2 Kíróníkà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, Sólómónì bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù lórí òkè Móríà, níbi tí Olúwa ti farahan bàbá a rẹ̀ Dáfídì. Ní ori ilẹ̀ ìpakà Áráúnà ará Jébúsì, ibi tí Dáfídì pèsè.

2 Kíróníkà 3

2 Kíróníkà 3:1-10